Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 18:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Ẹni tí ó rí aya fẹ́, rí ohun rere,Ó sì gba ojú rere lọ́dọ̀ Olúwa.

23. Tálákà ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú,Ṣùgbọ́n ọlọ́rọ̀ a dáhùn pẹ̀lú ìkanra.

24. Ènìyàn tí ó ní ọ̀rẹ́ púpọ̀ le è parunṢùgbọ́n ọ̀rẹ́ kan wà tí ó sún mọ́ ni tímọ́ tímọ́ ju arákùnrin.

Ka pipe ipin Òwe 18