Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 18:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Arákùnrin tí a ṣẹ̀ ṣòroó yípadà ju ìlú olódi lọ,ìjà sì dàbí ibodè ìlú olódi ńlá tí a ṣe.

Ka pipe ipin Òwe 18

Wo Òwe 18:19 ni o tọ