Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 18:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ènìyàn tí kò báni rẹ́ a máa lépa ìmọ̀ ara rẹ̀;ó kọjú ìjà sí gbogbo ìdájọ́ òdodo.

2. Aláìgbọ́n kò rí inú dídùn sí òyeṣùgbọn ó ní inú dídùn sí ṣíṣọ èrò tirẹ̀.

3. Nígbà ti ènìyàn búburú dé ni ẹ̀gàn dénígbà ti ẹ̀gàn dé ni ìtìjú dé.

Ka pipe ipin Òwe 18