Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 17:27-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Ènìyàn tó ní ìmọ̀ máa ń ṣọ́ra fún àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ń sọènìyàn olóye sì máa ń ní ṣùúrù.

28. Kódà aláìgbọ́n máa ń dàbí ọlọgbọ́n bí ó bá dákẹ́àti bí olóye bí ó bá fètèmétè.

Ka pipe ipin Òwe 17