Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 15:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Ẹni tí ó fetí sí ìbáwí tí ń fún ni ní ìyè,yóò wà ní àpéjọpọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n.

32. Ẹni tí ó kọ̀ ìbáwí kẹ́gàn ara rẹ̀,Ṣùgbọ́n ẹni tí ó gbọ́ ìbáwí yóò ní ìmọ̀ síi.

33. Ìbẹ̀rù Olúwa kọ́ ènìyàn ní ọgbọ́n,Ìrẹ̀lẹ̀ sì ni ó máa ń ṣáájú ọlá.

Ka pipe ipin Òwe 15