Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 13:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Ènìyàn rere a máa fi ogún sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀,ṣùgbọ́n, a kó ọrọ̀ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ pamọ́ fún àwọn olódodo.

23. Ilẹ̀ ẹ talákà le è mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ irè oko wáṣùgbọ́n àìsòdodo gbá gbogbo rẹ̀ lọ.

24. Ẹni tí ó fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀ṣùgbọ́n ẹni tí ó fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ yóò máa báa wí.

Ka pipe ipin Òwe 13