Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 13:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọlọ́gbọ́n ọmọ pa àṣẹ baba rẹ̀ mọ́ṣùgbọ́n ẹlẹ́gàn kò fetí sí ìbáwí.

2. Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ènìyàn ń gbádùn àwọn ohun rereṣùgbọ́n, aláìsòótọ́ ní ìfẹ́ ọkàn láti inú ìwà ipá.

Ka pipe ipin Òwe 13