Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jí ìwọ afẹ́fẹ́ àríwákí o sì wá, afẹ́fẹ́ gúṣù!Fẹ́ lórí ọgbà mi,kí àwọn òórùn dídùn inú rẹ lè rùn jáde.Jẹ́ kí olùfẹ́ mi wá sínú ọgbà a rẹ̀kí ó sì jẹ àṣàyàn èso rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 4

Wo Orin Sólómónì 4:16 ni o tọ