Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 4:12-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Arábìnrin mi ni ọgbà tí a sọ, arábinrin mi, ìyàwó miìṣun tí a sé mọ́, oríṣun tí a fi èdìdì dì.

13. Ohun ọ̀gbìn rẹ àgbàlá pàmóńgánéètì niti òun ti àṣàyàn èso; kípírésì àti nádì,

14. Nádì àti Ṣáfírónì,kálámúsì àti kínámónì,àti gbogbo igi olóòórùn dídùn,òjíá àti álóépẹ̀lú irú wọn.

15. Ìwọ ni ọgbà oríṣun, kànga omi ìyè,ìṣàn omi láti Lẹ́bánónì wá.

16. Jí ìwọ afẹ́fẹ́ àríwákí o sì wá, afẹ́fẹ́ gúṣù!Fẹ́ lórí ọgbà mi,kí àwọn òórùn dídùn inú rẹ lè rùn jáde.Jẹ́ kí olùfẹ́ mi wá sínú ọgbà a rẹ̀kí ó sì jẹ àṣàyàn èso rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 4