Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ẹni tí ń ti ijù jáde wábí ìkuku èéfíntí a ti fi òjíá àti tùràrí kùn lárapẹ̀lú gbogbo ètù olóòórùn oníṣòwò?

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 3

Wo Orin Sólómónì 3:6 ni o tọ