Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun búburú ni èyí jẹ́ nínú gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ oòrùn. Ìpín kan ṣoṣo ni ó ń dúró de gbogbo wọn, ọkàn ènìyàn pẹ̀lú kún fún ibi, ìṣínwín sì wà ní ọkàn wọn nígbà tí wọ́n wà láàyè àti nígbà tí wọ́n bá darapọ̀ mọ́ òkú.

Ka pipe ipin Oníwàásù 9

Wo Oníwàásù 9:3 ni o tọ