Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àyànmọ́ kan náà ni gbogbo wọn ń pín—olótìítọ́ àti òsìkà, rere àti ibi, mímọ́ àti àìmọ́, àwọn tí ó ń rúbọ àti àwọn tí kò rúbọ.Bí ó ti wà pẹ̀lú ọkùnrin rerebẹ́ẹ̀ náà ni ó wà pẹ̀lú ẹlẹ́ṣẹ̀bí ó ti wà pẹ̀lú àwọn tí ó ń ṣe ìbúrabẹ́ẹ̀ náà ni ó wà pẹ̀lú àwọn tí ó ń bẹ̀rù láti ṣe ìbúra.

Ka pipe ipin Oníwàásù 9

Wo Oníwàásù 9:2 ni o tọ