Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí, nígbà tí Ọlọ́run fún ẹnikẹ́ni ní ọrọ̀ àti ohun ìní, tí ó sì fún-un lágbára láti gbádùn wọn, láti gba ìpín rẹ̀ kí inú rẹ̀ sì dùn sí iṣẹ́ rẹ̀—ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí.

Ka pipe ipin Oníwàásù 5

Wo Oníwàásù 5:19 ni o tọ