Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ní láti jẹ́ ohun ìrántí pé ìpín ènìyàn rí bí i tẹranko ìpín ń dúró dè wọ́n. Bí ọ̀kan ti ń kú náà ni èkejì yóò kú. Àwọn méjèèjì ni irú èémí kan náà, ènìyàn kò ṣàn ju ẹranko lọ, nítorí pé aṣán ni yíyè jẹ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Oníwàásù 3

Wo Oníwàásù 3:19 ni o tọ