Mo rò nínú ọkàn mi,“Ọlọ́run yóò mú ṣẹ sí ìdájọ́Olótìítọ́ pẹ̀lú ẹlẹ́ṣẹ̀,Nítorí pé àsìkò yóò wà fún gbogbo iṣẹ́,àti àsìkò fún gbogbo ìṣe.”