Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo mọ̀ wí pé ohun gbogbo tí Ọlọ́run ṣe ni yóò wà títí láé, kò sí ohun tí a lè fi kún un tàbí kí a yọ kúrò nínú rẹ̀. Ọlọ́run ṣe èyí kí ènìyàn le è ní ìbẹ̀rù rẹ̀ ni.

Ka pipe ipin Oníwàásù 3

Wo Oníwàásù 3:14 ni o tọ