Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti ṣe ohun gbogbo dáradára ní àsìkò tirẹ̀, ó sì ti fi èrò nípa ayérayé sí ọkàn ọmọ ènìyàn, ṣíbẹ̀, wọn kò le ṣe àwárí ìdí ohun tí Ọlọ́run ti ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin.

Ka pipe ipin Oníwàásù 3

Wo Oníwàásù 3:11 ni o tọ