Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo kó wúrà àti wúrà jọ fún ara mi àti àwọn ohun ìṣúra ti ọba àti ìgbéríko. Mo ní àwọn akọrin ọkùnrin àti obìnrin. Mo sì ní onírúurú àwọn obìnrin tí ọkan ọkùnrin le e fà sí.

Ka pipe ipin Oníwàásù 2

Wo Oníwàásù 2:8 ni o tọ