Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ra àwọn ẹrú ọkùnrin àti àwọn ẹrú obìnrin, mo sì tún ní àwọn ẹrú mìíràn tí a bí sí ilé mi. Mo sì tún ní agbo àgùntàn ju ẹnikẹ́ni ní Jérúsálẹ́mù lọ.

Ka pipe ipin Oníwàásù 2

Wo Oníwàásù 2:7 ni o tọ