Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n dàbí ẹ̀gún, àkójọpọ̀ ọ̀rọ̀ wọn sì dàbí èso tí a kàn pọ̀ dáradára tí olùṣọ́-àgùntàn kan fi fún ni.

Ka pipe ipin Oníwàásù 12

Wo Oníwàásù 12:11 ni o tọ