Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 12:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Rántí Ẹlẹ́dàá rẹní ọjọ́ èwe rẹ,nígbà tí ọjọ́ ibi kò tíì déàti tí ọdún kò tíì ní ṣun mọ́ etílé, nígbà tí ìwọ yóò wí pé,“Èmi kò ní ìdùnnú nínú wọn”

2. Kí oòrùn àti ìmọ́lẹ̀àti òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ tó ṣókùnkùn,àti kí àwọ̀ṣánmọ̀ tó padà lẹ́yìn òjò;

Ka pipe ipin Oníwàásù 12