Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún irúgbìn rẹ ní òwúrọ̀ kùtùkùtù,má sì ṣe jẹ́ kí ọwọ́ rẹ ṣọ̀lẹ ní àṣálẹ́,nítorí ìwọ kò mọ èyí tí yóò ṣe rerebóyá èyí tàbí ìyẹntàbí àwọn méjèèjì ni yóò ṣe dáradára bákàn náà.

Ka pipe ipin Oníwàásù 11

Wo Oníwàásù 11:6 ni o tọ