Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 11:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Fún àkàrà rẹ ṣórí omi,nítorí lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, ìwọ yóò ríi padà

2. Fi ìpín fún méje, àní fún mẹ́jọ pẹ̀lú,nítorí ìwọ kò mọ ohun—ìparun tí ó le è wá ṣórí ilẹ̀

3. Bí àwọ̀ṣánmọ̀ bá kún fún omi,ayé ni wọ́n ń rọ òjò síBí igi wó sí ì hà Gúṣù tàbí sí ìhà àríwáníbi tí ó wó sí náà, ni yóò dùbúlẹ̀ sí.

4. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń wo afẹ́fẹ́ kò ní fúnrúgbìn;ẹnikẹ́ni tí ó bá ń wo àwọ̀ṣańmọ̀ kò ní kórè.

Ka pipe ipin Oníwàásù 11