Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí gbogbo àwọn ọkùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ gé àwọn ẹ̀ka igi wọn tẹ̀lé Ábímélékì. Wọ́n kó wọn ti ilé ìṣọ́ agbára níbi tí àwọn ènìyàn sá pamọ́ sí wọ́n sì fi iná síi pẹ̀lú gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wà níbẹ̀. Gbogbo àwọn ènìyàn náà tí ó tó ẹgbẹ̀rún ènìyàn lọ́kùnrin àti lóbìnrin sì kú.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:49 ni o tọ