Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun àti gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gun òkè Sálímónì lọ. Ó gé àwọn ẹ̀ka díẹ̀ pẹ̀lú àáké, ó gbé àwọn ẹ̀ka wọ̀nyí sí èjìká rẹ̀. Ó sọ fún àwọn ọmọ ogun rẹ̀ pé, “Ẹ ṣe ohun tí ẹ rí tí mo ń ṣe yìí ní kíákíá.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:48 ni o tọ