Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí tí ó bá jẹ́ pé ẹ̀yín ṣe ohun tí ó ní ọlá àti pẹ̀lú ẹ̀mí òtítọ́ ní fífi Ábímélékì jọba, tí ó bá ṣe pé ohun tí ó tọ́ ni ẹ ṣe sí Jérú-Báálì àti ìdílé rẹ̀, bí ẹ bá san ẹ̀san tó yẹ fún un.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:16 ni o tọ