Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Igi ẹ̀gún dá àwọn igi lóhùn pé, ‘Bí lótítọ́ ni ẹ bá fẹ́ yàn mí ní ọba yín. Ẹ sá àṣálà sí abẹ́ ìbòji mi; ṣùgbọ́n tí kì í bá ṣe bẹ́ẹ̀ jẹ́ kí ìná jáde láti inú igi ẹ̀gún kí ó sì jó àwọn igi Kédárì àti ti Lẹ́bánónì run!’

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:15 ni o tọ