Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n mú méjì nínú àwọn olórí àwọn ará Mídíánì, àwọn náà ni Órébù àti Ṣéébù. Wọ́n pa Órébù nínú àpáta Órébù, wọ́n sì pa Ṣéébù níbi tí àwọn ènìyàn ti mọ̀ fún wáìnì tí a ń pè ní ìfúntí Ṣéébù. Wọ́n lé àwọn ará Mídíánì, nígbà tí wọ́n gbé orí Órébù àti Ṣéébù tọ Gídíónì wá ẹni tí ó wà ní ìhà kejì Jọ́dánì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:25 ni o tọ