Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì tún ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn ìlú tí ó wà ní orí òkè Éfúráímù wí pé, “Ẹ jáde wá bá àwọn ará Mídíánì jà, kí ẹ tètè gba àwọn omi Jọ́dánì títí dé Bẹti Bárà kí wọ́n tó dé bẹ̀.”Báyìí ni a ṣe pe gbogbo ọkùnrin ológun Éfúráímù jáde tí wọ́n sì gba gbogbo àwọn àbáwọdò Jọ́dánì títí dé Bẹti Bárà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:24 ni o tọ