Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 6:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru ọjọ́ náà Olúwa wí fún un pé, mú akọ màlúù bàbá rẹ kejì láti inú agbo, akọ màlúù ọlọ́dún méje. Wó pẹpẹ Báálì baba rẹ lulẹ̀, kí o sì fọ́ ọ̀pá Áṣírà tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:25 ni o tọ