Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣísérà kó gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun irin rẹ̀ tí ṣe ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀run (900) àti gbogbo àwọn ènìyàn (ọmọ ogun) tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, láti Háróṣétì tí àwọn orílẹ̀ èdè wá sí ọ̀dọ̀ Kíṣónì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 4

Wo Onídájọ́ 4:13 ni o tọ