Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 3:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n dúró tí wọn sì ń retí, Éhúdù ti sálọ. Ó ti gba ibi tí wọ́n ti ń gbẹ́ òkúta lére, ó sì sálọ sí Ṣéírà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 3

Wo Onídájọ́ 3:26 ni o tọ