Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éhúdù lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ níbi tí ó ti jókòó ní iyàrá ìtura rẹ̀, Éhúdù sì wí fún-un pé: “Mo ní ọ̀rọ̀ kan fún ọ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.” Bí ọba sì ti dìde ní orí ìtẹ́ rẹ̀,

Ka pipe ipin Onídájọ́ 3

Wo Onídájọ́ 3:20 ni o tọ