Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n jáde tọ àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì lọ ní ọjọ́ kẹta wọ́n sì dúró ní ipò wọn, wọ́n sì dìde ogun sí Gíbíà bí wọ́n ti ṣe tẹ́lẹ̀ rí.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:30 ni o tọ