Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fínéhásì ọmọ Élíásárì ọmọ Árónì, ní ń ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ ní iwájú rẹ̀.) Wọ́n béèrè pé, “Ṣe àwa tún le lọ sí ogun pẹ̀lú Bẹ́ńjámínì arákùnrin wa tàbí kí a má lọ?” Olúwa dáhùn pé, “Ẹ lọ nítorí ní ọ̀la ni èmi yóò fi wọ́n lé e yín lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:28 ni o tọ