Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì jáde lọ láti bá àwọn ará Bẹ́ńjámínì jà wọ́n sì dúró ní ipò ogun sí wọn ní Gíbíà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:20 ni o tọ