Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Ísirẹ́lì lọ sí Bẹ́tẹ́lì (ilé Ọlọ́run) wọ́n sì béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run. Wọ́n wí pé, “Ta ni nínú wa tí yóò kọ́ kojú àwọn ará Bẹ́ńjámínì láti bá wọn jà?” Olúwa dáhùn pé, “Júdà ni yóò kọ́ lọ.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:18 ni o tọ