Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àárin àwọn ọmọ ogun wọ̀nyí ni ó ti ní àwọn ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin (700) àṣàyàn ọkùnrin tí wọ́n ń lo ọwọ́ òsì, tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dára débi pé wọ́n lè fi kànnàkànnà ba fọ́nrán òwú ní àìtàṣé (wọ́n jẹ́ ata má tàṣe).

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:16 ni o tọ