Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìbínú rẹ̀ sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì Olúwa fi wọ́n lé àwọn akónisìn lọ́wọ́ tí ó kó wọn ní ẹrú, tí ó sì bà wọ́n jẹ́. Ó sì tà wọ́n fún àwọn ọ̀ta wọn tí ó yí wọn ká àwọn ẹni tí wọn kò le dúró dè láti kọ ojú ìjà sí.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 2

Wo Onídájọ́ 2:14 ni o tọ