Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn méjèèjì sì jùmọ̀ jókòó wọn láti jọ jẹun àti láti jọ mu. Lẹ́yìn èyí ni baba ọmọbìnrin wí pé, “Jọ̀wọ́ dúró ní alẹ́ yìí kí o sì gbádùn ara rẹ.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:6 ni o tọ