Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 17:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkà bi í pé, “Níbo ni ó ti ń bọ̀?”Ó dáhùn pé, “Ọmọ Léfì ni mí láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù Júdà, mo sì ń wá ibi tí èmi yóò máa gbé.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 17

Wo Onídájọ́ 17:9 ni o tọ