Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkà sì sọ fún un wí pé, “Dúró lọ́dọ̀ mi (máa bá mi gbé) kí ìwọ sì jẹ́ baba mi àti àlùfáà fún mi, èmi ó sì máa fún ọ ní ṣékélì mẹ́wàá fàdákà ní ọdọọdún, pẹ̀lú aṣọ àti oúnjẹ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 17

Wo Onídájọ́ 17:10 ni o tọ