Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 17:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà òun dá sílífà náà padà fún ìyá rẹ̀, ìyá rẹ̀ sì mú igba (200) ṣékélì fàdákà, ó sì fún alágbẹ̀dẹ fàdákà ẹni tí ó fi wọ́n rọ ère fínfín àti ère dídà. Wọ́n sì kó wọn sí ilé Míkà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 17

Wo Onídájọ́ 17:4 ni o tọ