Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 16:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Sámúsónì ké pe Olúwa wí pé, “Olúwa Ọlọ́run ọ̀run àti ayé, rántí mi. Háà Ọlọ́run jọ̀wọ́ fi agbára fún mi lẹ́ẹ̀kan yìí sí i, kí èmi lè gbẹ̀san lára àwọn Fílístínì nítorí àwọn ojú mi méjèèjì.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 16

Wo Onídájọ́ 16:28 ni o tọ