Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 16:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dẹ̀lílà sì sọ fún un pé, “Èéṣe tí ìwọ fi wí pé, èmi fẹ́ràn rẹ, nígbà tí ìwọ kò fi ọkàn tán mi. Èyí ni ìgbà kẹta tí ìwọ ti tàn mí jẹ, tí ìwọ kò sì sọ àsírí ibi tí agbára ńlá rẹ gbé wà fún mi.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 16

Wo Onídájọ́ 16:15 ni o tọ