Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì fi ìhunṣọ dè wọ́n.Ó sì tún pè é pé, “Sámúsónì àwọn Fílístínì dé láti mú ọ.” Òun sì jí ní ojú oorun, ó sì fa ìdè ìhunṣọ náà tu pẹ̀lú ohun gbogbo tí wọ́n fi kàn án mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 16

Wo Onídájọ́ 16:14 ni o tọ