Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó tó di àṣálẹ́ ọjọ́ keje àwọn ọkùnrin ìlú náà sọ fún un pé,“Kí ni ó dùn ju oyin lọ?Kí ni ó sì lágbára ju kìnìún lọ?”Sámúsónì dá wọn lóhùn pé,“Bí kì í bá ṣe pé ẹ fi ọ̀dọ́ màlúù mi kọ ilẹ̀,ẹ̀yin kò bá tí mọ ìtumọ̀ sí àlọ́ mi.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 14

Wo Onídájọ́ 14:18 ni o tọ