Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ańgẹ́lì Olúwa náà kò tún fi ara rẹ̀ han Mánóà àti aya rẹ̀ mọ́, Mánóà wá mọ̀ pé ańgẹ́lì Olúwa ni.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:21 ni o tọ