Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 13:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀là ahọ́n iná ti là jáde láti ibi pẹpẹ ìrúbọ náà sí ọ̀run, ańgẹ́lì Olúwa gòkè re ọ̀run láàárin ahọ́n iná náà. Nígbà tí wọ́n rí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí, Mánóà àti aya rẹ̀ wólẹ̀ wọ́n sì dojú bolẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:20 ni o tọ