Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ní ọgbọ̀n (30) ọmọkùnrin àti ọgbọ̀n ọmọbìnrin fún àwọn tí kì í ṣe ẹ̀yà rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìyàwó, ó sì fẹ́ ọgbọ̀n àwọn ọmọbìnrin fún àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin lára àwọn tí kì í ṣe ẹ̀yà rẹ̀. Ó ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì fún ọdún méje.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 12

Wo Onídájọ́ 12:9 ni o tọ